Matiu 5:4
Matthew 5:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Alábùkún fún ni àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀, nítorí a ó tù wọ́n nínú.
Matthew 5:4 in English
Matthew 5:4 · Berean Standard Bible
Blessed are those who mourn, for they will be comforted.
Context
2Ó sì bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ wọn.
Ó wí pé, 3“Alábùkún fún ni àwọn òtòṣì ní ẹ̀mí,
nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run. 4Alábùkún fún ni àwọn tí ń ṣọ̀fọ̀,
nítorí a ó tù wọ́n nínú. 5Alábùkún fún ni àwọn ọlọ́kàn tútù,
nítorí wọn yóò jogún ayé. 6Alábùkún fún ni àwọn tí ebi ń pa
tí òǹgbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò yó.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.