Joṣua 21:22
Joshua 21:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Kibasaimu àti Beti-Horoni, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn jẹ́ ìlú mẹ́rin.
Joshua 21:22 in English
Joshua 21:22 · Berean Standard Bible
Kibzaim, and Beth-horon—four cities, together with their pasturelands.
Context
20Ìyókù ìdílé Kohati tí ó jẹ́ ọmọ Lefi ní a pín ìlú fún láti ara ẹ̀yà Efraimu. 21Ní ilẹ̀ òkè Efraimu wọ́n fún wọn ní:
Ṣekemu (tí ó jẹ́ ìlú ààbò fún apànìyàn) àti Geseri, 22Kibasaimu àti Beti-Horoni, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko wọn jẹ́ ìlú mẹ́rin. 23Láti ara ẹ̀yà Dani ni wọ́n ti fún wọn ní:
Elteke, Gibetoni, 24Aijaloni àti Gati-Rimoni, pẹ̀lú ilẹ̀ pápá oko tútù wọn jẹ́ ìlú mẹ́rin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.