Native Bible

Joshua 13:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

sí Heṣboni àti gbogbo ìlú rẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú Diboni, Bamoti Baali, Beti-Baali-Mioni,

Joshua 13:17 in English

Joshua 13:17 · Berean Standard Bible

to Heshbon and all its cities on the plateau, including Dibon, Bamoth-baal, Beth-baal-meon,

Context

15Èyí ni Mose fi fún ẹ̀yà Reubeni ni agbo ilé sí agbo ilé, 16láti agbègbè Aroeri ní etí Arnoni Jọ́ọ́jì àti láti ìlú tí ń bẹ láàrín Jọ́ọ́jì, àti gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìkọjá Medeba 17sí Heṣboni àti gbogbo ìlú rẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú Diboni, Bamoti Baali, Beti-Baali-Mioni, 18Jahisa, Kedemoti, Mefaati, 19Kiriataimu, Sibma, Sereti Ṣahari lórí òkè ní àfonífojì.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.