Native Bible

Joshua 13:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jahisa, Kedemoti, Mefaati,

Joshua 13:18 in English

Joshua 13:18 · Berean Standard Bible

Jahaz, Kedemoth, Mephaath,

Context

16láti agbègbè Aroeri ní etí Arnoni Jọ́ọ́jì àti láti ìlú tí ń bẹ láàrín Jọ́ọ́jì, àti gbogbo pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ìkọjá Medeba 17sí Heṣboni àti gbogbo ìlú rẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, pẹ̀lú Diboni, Bamoti Baali, Beti-Baali-Mioni, 18Jahisa, Kedemoti, Mefaati, 19Kiriataimu, Sibma, Sereti Ṣahari lórí òkè ní àfonífojì. 20Beti-Peori, gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ Pisga, àti Beti-Jeṣimoti

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.