Native Bible

Job 6:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Agbára mi ha ṣe agbára òkúta bí? Ẹran-ara mi í ṣe idẹ?

Job 6:12 in English

Job 6:12 · Berean Standard Bible

Is my strength like that of stone, or my flesh made of bronze?

Context

10Nígbà náà ní èmi ìbá ní ìtùnú síbẹ̀, àní, èmi ìbá mú ọkàn mi le nínú ìbànújẹ́ mi ti kò dá ni sí: nítorí èmi kò fi ọ̀rọ̀ ẹni mímọ́ ni sin rí. 11“Kí ní agbára mi tí èmi ó fi retí? Kí sì ní òpin mi tí èmi ó fi ní sùúrù? 12Agbára mi ha ṣe agbára òkúta bí? Ẹran-ara mi í ṣe idẹ? 13Ìrànlọ́wọ́ mi kò ha wà nínú mi: ọgbọ́n kò ha ti sálọ kúrò lọ́dọ̀ mi bí? 14“Ẹni tí àyà rẹ̀ yọ́ dànù, ta ni a bá máa ṣàánú fún láti ọ̀dọ̀ ọ̀rẹ́ rẹ̀ wá, kí ó má ba à kọ ìbẹ̀rù Olódùmarè sílẹ̀?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.