Native Bible

Job 6:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Jobu sì dáhùn ó si wí pé,

Job 6:1 in English

Context

1Jobu sì dáhùn ó si wí pé, 2“Háà! À bá lè wọ́n ìbìnújẹ́ mi nínú òsùwọ̀n, kí a sì le gbé ọ̀fọ̀ mi lé orí òsùwọ̀n ṣọ̀kan pọ̀! 3Ǹjẹ́ nísinsin yìí, ìbá wúwo jú iyanrìn òkun lọ, nítorí náà ni ọ̀rọ̀ mi ṣe ń tàsé.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.