Native Bible

Job 5:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Ó jẹ́ pé nísinsin yìí bí ẹnìkan bá wà tí yóò dá wa lóhùn? Tàbí ta ni nínú àwọn ènìyàn mímọ́ tí ìwọ ó yípadà sí?

Job 5:1 in English

Job 5:1 · Berean Standard Bible

“Call out if you please, but who will answer? To which of the holy ones will you turn?

Context

1“Ó jẹ́ pé nísinsin yìí bí ẹnìkan bá wà tí yóò dá wa lóhùn? Tàbí ta ni nínú àwọn ènìyàn mímọ́ tí ìwọ ó yípadà sí? 2Nítorí pé ìbínú pa aláìmòye, ìrunú a sì pa òpè ènìyàn. 3Èmi ti rí aláìmòye ti ó ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lulẹ̀, ṣùgbọ́n lójúkan náà mo fi ibùjókòó rẹ̀ bú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.