Jobu 5:2
Job 5:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé ìbínú pa aláìmòye, ìrunú a sì pa òpè ènìyàn.
Job 5:2 in English
Job 5:2 · Berean Standard Bible
For resentment kills a fool, and envy slays the simple.
Context
1“Ó jẹ́ pé nísinsin yìí bí ẹnìkan bá wà tí yóò dá wa lóhùn?
Tàbí ta ni nínú àwọn ènìyàn mímọ́ tí ìwọ ó yípadà sí? 2Nítorí pé ìbínú pa aláìmòye,
ìrunú a sì pa òpè ènìyàn. 3Èmi ti rí aláìmòye ti ó ta gbọ̀nọ́ngbọ̀nọ́n lulẹ̀,
ṣùgbọ́n lójúkan náà mo fi ibùjókòó rẹ̀ bú. 4Àwọn ọmọ rẹ̀ kò jìnnà sí ewu,
a sì tẹ̀ wọ́n mọ́lẹ̀ lójú ibodè,
bẹ́ẹ̀ ni kò sí aláàbò kan.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.