Native Bible

Job 41:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó ká irin sí ibi koríko gbígbẹ àti idẹ si bi igi híhù.

Job 41:27 in English

Job 41:27 · Berean Standard Bible

He regards iron as straw and bronze as rotten wood.

Context

25Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù; nítorí ìbẹ̀rù ńlá, wọ́n dààmú. 26Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà, ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an. 27Ó ká irin sí ibi koríko gbígbẹ àti idẹ si bi igi híhù. 28Ọfà kò lè mú un sá; òkúta kànnakánná lọ́dọ̀ rẹ̀ dàbí àgékù koríko. 29Ó ka ẹṣin sí bí àgékù ìdì koríko; ó rẹ́rìn-ín sí mímì ọ̀kọ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.