Jobu 41:26
Job 41:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà, ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an.
Job 41:26 in English
Job 41:26 · Berean Standard Bible
The sword that reaches him has no effect, nor does the spear or dart or arrow.
Context
24Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta,
àní, ó le bi ìyá ọlọ. 25Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù;
nítorí ìbẹ̀rù ńlá, wọ́n dààmú. 26Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà,
ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an. 27Ó ká irin sí ibi koríko gbígbẹ
àti idẹ si bi igi híhù. 28Ọfà kò lè mú un sá;
òkúta kànnakánná lọ́dọ̀ rẹ̀ dàbí àgékù koríko.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.