Jobu 41:24
Job 41:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta, àní, ó le bi ìyá ọlọ.
Job 41:24 in English
Job 41:24 · Berean Standard Bible
His chest is as hard as a rock, as hard as a lower millstone!
Context
22Ní ọrùn rẹ̀ ní agbára kù sí,
àti ìbànújẹ́ àyà sì padà di ayọ̀ níwájú rẹ̀. 23Jabajaba ẹran rẹ̀ dìjọ pọ̀,
wọ́n múra gírí fún ara wọn, a kò lè sí wọn ní ipò. 24Àyà rẹ̀ dúró gbagidi bí òkúta,
àní, ó le bi ìyá ọlọ. 25Nígbà tí ó bá gbé ara rẹ̀ sókè, àwọn alágbára bẹ̀rù;
nítorí ìbẹ̀rù ńlá, wọ́n dààmú. 26Ọ̀kọ̀ tàbí idà, tàbí ọfà,
ẹni tí ó ṣá a kò lè rán an.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.