Native Bible

Job 30:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi ti di arákùnrin ìkookò, èmi di ẹgbẹ́ àwọn ògòǹgò.

Job 30:29 in English

Job 30:29 · Berean Standard Bible

I have become a brother of jackals,* a companion of ostriches.*

Context

27Ikùn mí n ru kò sì sinmi, ọjọ́ ìpọ́njú ti dé bá mi. 28Èmí ń rìn kiri nínú ọ̀fọ̀, ṣùgbọ́n kì í ṣe nínú oòrùn; èmi dìde dúró ní àwùjọ mo sì kígbe fún ìrànlọ́wọ́. 29Èmi ti di arákùnrin ìkookò, èmi di ẹgbẹ́ àwọn ògòǹgò. 30Àwọ̀ mi di dúdú ní ara mi; egungun mi sì jórun fún ooru. 31Ohun èlò orin mi pẹ̀lú sì di ti ọ̀fọ̀, àti ìpè orin mi sì di ohùn àwọn tí ń sọkún.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.