Jobu 3:22
Job 3:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ẹni tí ó yọ̀ gidigidi, tí inú wọ́n sì dùn nígbà tí wọ́n wá ibojì òkú rí?
Job 3:22 in English
Job 3:22 · Berean Standard Bible
who rejoice and greatly exult when they can find the grave?
Context
20“Nítorí kí ni a ṣe fi ìmọ́lẹ̀ fún òtòṣì,
àti ìyè fún ọlọ́kàn kíkorò, 21tí wọ́n dúró de ikú, ṣùgbọ́n òun kò wá,
tí wọ́n wá a jù ìṣúra tí a bò mọ́lẹ̀ pamọ́ lọ. 22Ẹni tí ó yọ̀ gidigidi,
tí inú wọ́n sì dùn nígbà tí wọ́n wá ibojì òkú rí? 23Kí ni a fi ìmọ́lẹ̀ fún ẹni
tí ọ̀nà rẹ̀ fi ara pamọ́ fún,
tí Ọlọ́run sì ṣọgbà dí mọ́ ká? 24Nítorí pé èémí-ẹ̀dùn wà ṣáájú oúnjẹ mi;
ìkérora mi sì tú jáde bí omi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.