Native Bible

Job 3:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èéṣe tí orúnkún wá pàdé mi, tàbí ọmú tí èmi yóò mu?

Job 3:12 in English

Job 3:12 · Berean Standard Bible

Why were there knees to receive me, and breasts that I should be nursed?

Context

10nítorí tí kò sé ìlẹ̀kùn inú ìyá mi, láti pa ìbànújẹ́ rẹ́ ní ojú mi. 11“Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá, tàbí tí èmi kò kú ní ìgbà tí mo ti inú jáde wá? 12Èéṣe tí orúnkún wá pàdé mi, tàbí ọmú tí èmi yóò mu? 13Ǹjẹ́ nísinsin yìí èmi ìbá ti dùbúlẹ̀ jẹ́ẹ́; èmi ìbá ti sùn, èmi ìbá ti sinmi 14pẹ̀lú àwọn ọba àti ìgbìmọ̀ ayé tí wọ́n mọ ilé fún ara wọn wá dùbúlẹ̀ nínú ìsọdahoro.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.