Jobu 3:11
Job 3:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá, tàbí tí èmi kò kú ní ìgbà tí mo ti inú jáde wá?
Job 3:11 in English
Job 3:11 · Berean Standard Bible
Why did I not perish at birth; why did I not die as I came from the womb?
Context
9Kí ìràwọ̀ òwúrọ̀ ọjọ́ rẹ̀ kí ó ṣókùnkùn;
kí ó má wá ìmọ́lẹ̀, ṣùgbọ́n kí ó máa mọ́ sí i,
bẹ́ẹ̀ ni kí ó má ṣe rí àfẹ̀mọ́júmọ́ 10nítorí tí kò sé ìlẹ̀kùn inú ìyá mi,
láti pa ìbànújẹ́ rẹ́ ní ojú mi. 11“Èéṣe tí èmi kò fi kú láti inú wá,
tàbí tí èmi kò kú ní ìgbà tí mo ti inú jáde wá? 12Èéṣe tí orúnkún wá pàdé mi,
tàbí ọmú tí èmi yóò mu? 13Ǹjẹ́ nísinsin yìí èmi ìbá ti dùbúlẹ̀ jẹ́ẹ́;
èmi ìbá ti sùn, èmi ìbá ti sinmi
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.