Native Bible

Job 23:16 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí pé Ọlọ́run ti pá mi ní àyà, Olódùmarè sì ń dààmú mi.

Job 23:16 in English

Job 23:16 · Berean Standard Bible

God has made my heart faint; the Almighty has terrified me.

Context

14Nítòótọ́ ohun tí a ti yàn fún mi ní í ṣe; ọ̀pọ̀lọpọ̀ irú ohun bẹ́ẹ̀ ni ó wà ní ọwọ́ rẹ̀. 15Nítorí náà ni ara kò ṣe rọ̀ mí níwájú rẹ̀; nígbà tí mo bá rò ó, ẹ̀rù a bà mi. 16Nítorí pé Ọlọ́run ti pá mi ní àyà, Olódùmarè sì ń dààmú mi. 17Nítorí tí a kò tí ì ké mi kúrò níwájú òkùnkùn, bẹ́ẹ̀ ni kò pa òkùnkùn biribiri mọ́ kúrò níwájú mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.