Native Bible

Job 23:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí tí a kò tí ì ké mi kúrò níwájú òkùnkùn, bẹ́ẹ̀ ni kò pa òkùnkùn biribiri mọ́ kúrò níwájú mi.

Job 23:17 in English

Job 23:17 · Berean Standard Bible

Yet I am not silenced by the darkness, by the thick darkness that covers my face.

Context

15Nítorí náà ni ara kò ṣe rọ̀ mí níwájú rẹ̀; nígbà tí mo bá rò ó, ẹ̀rù a bà mi. 16Nítorí pé Ọlọ́run ti pá mi ní àyà, Olódùmarè sì ń dààmú mi. 17Nítorí tí a kò tí ì ké mi kúrò níwájú òkùnkùn, bẹ́ẹ̀ ni kò pa òkùnkùn biribiri mọ́ kúrò níwájú mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.