Jobu 22:28
Job 22:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ; ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ.
Job 22:28 in English
Job 22:28 · Berean Standard Bible
Your decisions will be carried out, and light will shine on your ways.
Context
26Lóòtítọ́ nígbà náà ní ìwọ ó ní inú dídùn nínú Olódùmarè,
ìwọ ó sì gbé ojú rẹ sókè sọ́dọ̀ Ọlọ́run. 27Bí ìwọ bá gbàdúrà rẹ sọ́dọ̀ rẹ̀, yóò sì gbọ́ tìrẹ,
ìwọ ó sì san ẹ̀jẹ́ rẹ. 28Ìwọ ó sì gbìmọ̀ ohun kan pẹ̀lú, yóò sì fi ìdí múlẹ̀ fún ọ;
ìmọ́lẹ̀ yóò sì mọ́ sípa ọ̀nà rẹ. 29Nígbà tí ipa ọ̀nà rẹ bá lọ sísàlẹ̀,
nígbà náà ni ìwọ o wí pé, ‘Ìgbésókè ń bẹ!’
Ọlọ́run yóò sì gba onírẹ̀lẹ̀ là! 30Yóò gba ẹni tí kì í ṣe aláìjẹ̀bi là,
a ó sì gbà á nípa mímọ́ ọwọ́ rẹ̀.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.