Jobu 21:7
Job 21:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé, tí wọ́n gbó, àní tí wọ́n di alágbára ní ipa?
Job 21:7 in English
Job 21:7 · Berean Standard Bible
Why do the wicked live on, growing old and increasing in power?
Context
5Ẹ wò mí fín, kí ẹnu kí ó sì yà yín,
kí ẹ sì fi ọwọ́ lé ẹnu yín. 6Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí,
ìwárìrì sì mú mi lára. 7Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé,
tí wọ́n gbó, àní tí wọ́n di alágbára ní ipa? 8Irú-ọmọ wọn fi ìdí kalẹ̀ ní ojú
wọn pẹ̀lú wọn, àti ọmọ ọmọ wọn ní ojú wọn. 9Ilé wọn wà láìní ewu àti ẹ̀rù,
bẹ́ẹ̀ ni ọ̀pá ìbínú Ọlọ́run kò sí lára wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.