Native Bible

Job 21:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí, ìwárìrì sì mú mi lára.

Job 21:6 in English

Job 21:6 · Berean Standard Bible

When I remember, terror takes hold, and my body trembles in horror.

Context

4“Àròyé mi ha ṣe sí ènìyàn bí? Èétise tí ọkàn mi kì yóò fi ṣe àìbalẹ̀? 5Ẹ wò mí fín, kí ẹnu kí ó sì yà yín, kí ẹ sì fi ọwọ́ lé ẹnu yín. 6Àní nígbà tí mo rántí, ẹ̀rù bà mí, ìwárìrì sì mú mi lára. 7Nítorí kí ní ènìyàn búburú fi wà ní ayé, tí wọ́n gbó, àní tí wọ́n di alágbára ní ipa? 8Irú-ọmọ wọn fi ìdí kalẹ̀ ní ojú wọn pẹ̀lú wọn, àti ọmọ ọmọ wọn ní ojú wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.