Native Bible

Job 16:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìgbà náà ní Jobu dáhùn, ó sì wí pé,

Job 16:1 in English

Context

1Ìgbà náà ní Jobu dáhùn, ó sì wí pé, 2“Èmi ti gbọ́ irú ohun púpọ̀ bẹ́ẹ̀ rí ayọnilẹ́nu onítùnú ènìyàn ní gbogbo yín. 3Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin? Tàbí kí ni ó gbó ọ láyà tí ìwọ fi dáhùn?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.