Jobu 16:3
Job 16:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin? Tàbí kí ni ó gbó ọ láyà tí ìwọ fi dáhùn?
Job 16:3 in English
Job 16:3 · Berean Standard Bible
Is there no end to your long-winded speeches? What provokes you to continue testifying?
Context
1Ìgbà náà ní Jobu dáhùn, ó sì wí pé, 2“Èmi ti gbọ́ irú ohun púpọ̀ bẹ́ẹ̀ rí
ayọnilẹ́nu onítùnú ènìyàn ní gbogbo yín. 3Ọ̀rọ̀ asán lè ni òpin?
Tàbí kí ni ó gbó ọ láyà tí ìwọ fi dáhùn? 4Èmi pẹ̀lú le sọ bí ẹ̀yin;
bí ọkàn yín bá wà ní ipò ọkàn mi,
èmi le sọ ọ̀rọ̀ dáradára púpọ̀ sí yín ní ọrùn,
èmi a sì mi orí mi sí i yín. 5Èmi ìbá fi ọ̀rọ̀ ẹnu mi gbà yín ni ìyànjú,
àti ṣíṣí ètè mi ìbá sì tu ìbìnújẹ́ yín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.