Jobu 15:26
Job 15:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
ó súre, ó sì fi ẹ̀yìn gíga, àní fi ike-kókó àpáta rẹ̀ tí ó nípọn kọlù ú.
Job 15:26 in English
Job 15:26 · Berean Standard Bible
rushing headlong at Him with a thick, studded shield.
Context
24Ìpọ́njú pẹ̀lú ìrora ọkàn yóò mú un bẹ̀rù,
wọ́n ó sì ṣẹ́gun rẹ̀ bi ọba ti ìmúra ogun. 25Nítorí pé ó ti nawọ́ rẹ̀ jáde lòdì sí Ọlọ́run,
ó sì múra rẹ̀ le lòdì sí Olódùmarè, 26ó súre, ó sì fi ẹ̀yìn gíga,
àní fi ike-kókó àpáta rẹ̀ tí ó nípọn kọlù ú. 27“Nítorí tí òun fi ọ̀rá rẹ̀ bo ara rẹ̀ lójú,
o sì ṣe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹran sí ẹ̀gbẹ́ rẹ̀. 28Òun sì gbé inú ahoro ìlú,
àti nínú ilẹ̀ tí ènìyàn kò gbé mọ́,
tí ó múra tán láti di àlàpà.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.