Jeremiah 4:25
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mo wò yíká n kò rí ẹnìkan; gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run ló ti fò lọ.
Jeremiah 4:25 in English
Jeremiah 4:25 · Berean Standard Bible
I looked, and no man was left; all the birds of the air had fled.
Context
23Mo bojú wo ayé,
ó sì wà ní júujùu, ó sì ṣófo
àti ní ọ̀run,
ìmọ́lẹ̀ wọn kò sì ṣí. 24Mo wo àwọn òkè ńlá,
wọ́n wárìrì;
gbogbo òkè kéékèèké mì jẹ̀jẹ̀. 25Mo wò yíká n kò rí ẹnìkan;
gbogbo ẹyẹ ojú ọ̀run ló ti fò lọ. 26Mo bojú wò, ilẹ̀ eléso, ó sì di aṣálẹ̀
gbogbo àwọn ìlú inú rẹ̀ sì ṣubú sínú ìparun
níwájú Olúwa àti níwájú ríru ìbínú rẹ̀. 27Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
“Gbogbo ìlú náà yóò sì di ahoro,
síbẹ̀ èmi kì yóò pa á run pátápátá.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.