Isaiah 23:1
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire. Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi! Nítorí a ti pa Tire run láìsí ilé tàbí èbúté. Láti ilẹ̀ Saipurọsi ni ọ̀rọ̀ ti wá sọ́dọ̀ wọn.
Isaiah 23:1 in English
Isaiah 23:1 · Berean Standard Bible
This is the burden against Tyre: Wail, O ships of Tarshish,* for Tyre is laid waste, without house or harbor. Word has reached them from the land of Cyprus.*
Context
1Ọ̀rọ̀-ìmọ̀ tí ó kan Tire.
Hu, ìwọ ọkọ̀ ojú omi Tarṣiṣi!
Nítorí a ti pa Tire run
láìsí ilé tàbí èbúté.
Láti ilẹ̀ Saipurọsi ni
ọ̀rọ̀ ti wá sọ́dọ̀ wọn. 2Dákẹ́ jẹ́ẹ́, ẹ̀yin ènìyàn erékùṣù
àti ẹ̀yin oníṣòwò ti Sidoni,
ẹ̀yin tí àwọn a wẹ Òkun ti sọ dọlọ́rọ̀. 3Láti orí àwọn omi ńlá
ni irúgbìn ìyẹ̀fun ti ilẹ̀ Ṣihori ti wá;
ìkórè ti odò Naili ni owóòná Tire,
òun sì ti di ibùjókòó ọjà fún àwọn orílẹ̀-èdè.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.