Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìjì ni yóò gbá wọn lọ. Gbogbo ìrúbọ wọn yóò sì kó ìtìjú bá wọn.

Hosea 4:19 in English

Hosea 4:19 · Berean Standard Bible

The whirlwind has wrapped them * in its wings, and their sacrifices will bring them shame.

Context

17Efraimu ti darapọ̀ mọ́ òrìṣà, ẹ fi sílẹ̀! 18Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán, wọ́n tún tẹ̀síwájú nínú àgbèrè. Àwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ. 19Ìjì ni yóò gbá wọn lọ. Gbogbo ìrúbọ wọn yóò sì kó ìtìjú bá wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.