Hosea 4:18
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán, wọ́n tún tẹ̀síwájú nínú àgbèrè. Àwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ.
Hosea 4:18 in English
Hosea 4:18 · Berean Standard Bible
When their liquor is gone, they turn to prostitution; their rulers * dearly love disgrace.
Context
16Àwọn ọmọ Israẹli ṣe agídí
bí alágídí ọmọ màlúù.
Báwo wá ni Olúwa ṣe fẹ́ bọ́ wọn
bí àgùntàn ní pápá oko tútù? 17Efraimu ti darapọ̀ mọ́
òrìṣà, ẹ fi sílẹ̀! 18Bí ohun mímu wọn bá tilẹ̀ tán,
wọ́n tún tẹ̀síwájú nínú àgbèrè.
Àwọn olórí wọn fẹ́ràn ohun ìtìjú ju ohun ìyìn lọ. 19Ìjì ni yóò gbá wọn lọ.
Gbogbo ìrúbọ wọn yóò sì kó ìtìjú bá wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.