Native Bible

Genesis 6:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Noa sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta, Ṣemu, Hamu àti Jafeti.

Genesis 6:10 in English

Genesis 6:10 · Berean Standard Bible

And Noah had three sons: Shem, Ham, and Japheth.

Context

8Ṣùgbọ́n, Noa rí ojúrere Olúwa. 9Wọ̀nyí ni ìtàn Noa. Noa nìkan ni ó jẹ́ olóòótọ́ ènìyàn àti ẹni tí ó pé ní ìgbà ayé rẹ̀, ó sì fi òtítọ́ bá Ọlọ́run rìn. 10Noa sì bí ọmọkùnrin mẹ́ta, Ṣemu, Hamu àti Jafeti. 11Ayé sì kún fún ìbàjẹ́ gidigidi ní ojú Ọlọ́run, ó sì kún fún ìwà ipá pẹ̀lú. 12Ọlọ́run sì rí bí ayé ti bàjẹ́ tó, nítorí àwọn ènìyàn inú ayé ti bá ara wọn jẹ́ ní gbogbo ọ̀nà wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.