Native Bible

Genesis 36:29 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn wọ̀nyí ni olórí ìdílé Hori: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana,

Genesis 36:29 in English

Genesis 36:29 · Berean Standard Bible

These are the chiefs of the Horites: Chiefs Lotan, Shobal, Zibeon, Anah,

Context

27Àwọn ọmọ Eseri: Bilhani, Saafani àti Akani. 28Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi àti Arani. 29Àwọn wọ̀nyí ni olórí ìdílé Hori: Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, 30Diṣoni Eseri, àti Diṣani. Àwọn ni olórí ìdílé àwọn ará Hori gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ní ilẹ̀ Seiri. 31Àwọn wọ̀nyí ni ọba tí ó jẹ ní Edomu kí ó tó di pé ọba kankan jẹ lórí Israẹli:

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.