Gẹnẹsisi 36:28
Genesis 36:28 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Diṣani ni: Usi àti Arani.
Genesis 36:28 in English
Genesis 36:28 · Berean Standard Bible
These are the sons of Dishan: Uz and Aran.
Context
26Àwọn ọmọ Diṣoni ni:
Hemdani, Eṣbani, Itrani àti Kerani. 27Àwọn ọmọ Eseri:
Bilhani, Saafani àti Akani. 28Àwọn ọmọ Diṣani ni:
Usi àti Arani. 29Àwọn wọ̀nyí ni olórí ìdílé Hori:
Lotani, Ṣobali, Sibeoni, Ana, 30Diṣoni Eseri, àti Diṣani.
Àwọn ni olórí ìdílé àwọn ará Hori gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn ní ilẹ̀ Seiri.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.