Native Bible

Genesis 24:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ni ọkùnrin náà tẹríba, ó sì sin Olúwa,

Genesis 24:26 in English

Genesis 24:26 · Berean Standard Bible

Then the man bowed down and worshiped the LORD,

Context

24Ó dáhùn pé, “Betueli ọmọ tí Milka bí fún Nahori ni baba mi.” 25Ó sì fi kún un pé, “Àwa ní koríko àti ṣakaṣaka tó pẹ̀lú, àti ààyè láti wọ̀ sí.” 26Nígbà náà ni ọkùnrin náà tẹríba, ó sì sin Olúwa, 27wí pe, “Olùbùkún ni fún Olúwa, Ọlọ́run Abrahamu olúwa mi ti kò jẹ́ kí àánú àti òtítọ́ rẹ̀ kí ó yẹ̀ lọ́dọ̀ olúwa mi. Ní ti èmi Olúwa ti darí ìrìnàjò mi sí ilé ìbátan olúwa mi.” 28Ọmọbìnrin náà sì sáré, ó sì lọ sọ ohun gbogbo wọ̀nyí fún àwọn ará ilé ìyá rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.