Esra 8:9
Ezra 8:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nínú àwọn ọmọ Joabu: Obadiah ọmọ Jehieli àti ogún ó lé nígba ó dín méjì (218) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;
Ezra 8:9 in English
Ezra 8:9 · Berean Standard Bible
from the descendants of Joab, Obadiah son of Jehiel, and with him 218 men;
Context
7nínú àwọn ọmọ Elamu:
Jeṣaiah ọmọ Ataliah àwọn àádọ́rin ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 8nínú àwọn ọmọ Ṣefatia:
Sebadiah ọmọ Mikaeli, àti ọgọ́rin ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 9nínú àwọn ọmọ Joabu:
Obadiah ọmọ Jehieli àti ogún ó lé nígba ó dín méjì (218) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 10nínú àwọn ọmọ Bani:
Ṣelomiti ọmọ Josafiah, àti ọgọ́jọ ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 11nínú àwọn ọmọ Bebai:
Sekariah ọmọ Bebai àti ọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú rẹ̀;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.