Esra 8:11
Ezra 8:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nínú àwọn ọmọ Bebai: Sekariah ọmọ Bebai àti ọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú rẹ̀;
Ezra 8:11 in English
Ezra 8:11 · Berean Standard Bible
from the descendants of Bebai, Zechariah son of Bebai, and with him 28 men;
Context
9nínú àwọn ọmọ Joabu:
Obadiah ọmọ Jehieli àti ogún ó lé nígba ó dín méjì (218) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 10nínú àwọn ọmọ Bani:
Ṣelomiti ọmọ Josafiah, àti ọgọ́jọ ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 11nínú àwọn ọmọ Bebai:
Sekariah ọmọ Bebai àti ọkùnrin méjìdínlọ́gbọ̀n pẹ̀lú rẹ̀; 12nínú àwọn ọmọ Asgadi:
Johanani ọmọ Hakatani, àti àádọ́fà ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 13nínú àwọn ọmọ Adonikami:
àwọn ti ó gbẹ̀yìn, tì orúkọ wọn ń jẹ́ Elifaleti, Jeieli àti Ṣemaiah, àti ọgọ́ta ọkùnrin pẹ̀lú wọn;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.