Esra 8:7
Ezra 8:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nínú àwọn ọmọ Elamu: Jeṣaiah ọmọ Ataliah àwọn àádọ́rin ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;
Ezra 8:7 in English
Ezra 8:7 · Berean Standard Bible
from the descendants of Elam, Jeshaiah son of Athaliah, and with him 70 men;
Context
5nínú àwọn ọmọ Sattu:
Ṣekaniah ọmọ Jahasieli àti àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 6nínú àwọn ọmọ Adini:
Ebedi ọmọ Jonatani, àti àádọ́ta ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 7nínú àwọn ọmọ Elamu:
Jeṣaiah ọmọ Ataliah àwọn àádọ́rin ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 8nínú àwọn ọmọ Ṣefatia:
Sebadiah ọmọ Mikaeli, àti ọgọ́rin ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 9nínú àwọn ọmọ Joabu:
Obadiah ọmọ Jehieli àti ogún ó lé nígba ó dín méjì (218) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.