Native Bible

Ezra 2:38 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)

Ezra 2:38 in English

Ezra 2:38 · Berean Standard Bible

the descendants of Pashhur, 1,247;

Context

36Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 37Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 38Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 39Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017). 40Àwọn ọmọ Lefi. Àwọn ọmọ Jeṣua àti Kadmieli (ti ìdílé Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.