Native Bible

Ezra 2:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)

Ezra 2:36 in English

Ezra 2:36 · Berean Standard Bible

The priests: The descendants of Jedaiah (through the house of Jeshua), 973;

Context

34Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345) 35Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630). 36Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 37Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 38Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.