Native Bible

Ezra 2:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)

Ezra 2:37 in English

Ezra 2:37 · Berean Standard Bible

the descendants of Immer, 1,052;

Context

35Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630). 36Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 37Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 38Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 39Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.