Native Bible

Ezra 2:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630).

Ezra 2:35 in English

Ezra 2:35 · Berean Standard Bible

and the descendants of Senaah, 3,630.

Context

33Lodi, Hadidi àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé márùn-ún (725) 34Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345) 35Senaa jẹ́ egbèji dín lógún ó lé ọgbọ̀n (3,630). 36Àwọn àlùfáà. Àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 37Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.