Esra 10:21
Ezra 10:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nínú ìran Harimu: Maaseiah, Elijah, Ṣemaiah, Jehieli àti Ussiah.
Ezra 10:21 in English
Ezra 10:21 · Berean Standard Bible
From the descendants of Harim: Maaseiah, Elijah, Shemaiah, Jehiel, and Uzziah.
Context
19Gbogbo wọn ni wọ́n ṣe ìpinnu láti lé àwọn ìyàwó wọn lọ, wọ́n sì fi àgbò kan láàrín agbo ẹran lélẹ̀ fún ẹ̀bi wọn gẹ́gẹ́ bí ọrẹ ẹ̀ṣẹ̀. 20Nínú ìran Immeri:
Hanani àti Sebadiah. 21Nínú ìran Harimu:
Maaseiah, Elijah, Ṣemaiah, Jehieli àti Ussiah. 22Nínú ìran Paṣuri:
Elioenai, Maaseiah, Iṣmaeli, Netaneli, Josabadi àti Eleasa. 23Lára àwọn ọmọ Lefi:
Josabadi, Ṣimei, Kelaiah (èyí tí í ṣe Kelita), Petahiah, Juda àti Elieseri.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.