Esekiẹli 3:2
Ezekiel 3:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mo sì ya ẹnu mi, ó sì mú mi jẹ ìwé kíká náà.
Ezekiel 3:2 in English
Ezekiel 3:2 · Berean Standard Bible
So I opened my mouth, and He fed me the scroll.
Context
1Síwájú sí i, ó sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, jẹ ohun tí ó wà níwájú rẹ, jẹ ìwé kíká yìí; kí o sì lọ fi bá ilé Israẹli sọ̀rọ̀.” 2Mo sì ya ẹnu mi, ó sì mú mi jẹ ìwé kíká náà. 3Ó tún sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, jẹ ìwé kíká tí mo fún ọ yìí, fi bọ́ inú àti ikùn rẹ.” Nígbà náà ni mo jẹ ẹ́, dídùn rẹ̀ dàbí oyin ní ẹnu mi. 4Ó sì tún sọ fún mi pé, “Ọmọ ènìyàn, lọ ni ìsinsin yìí bá mi sọ ọ̀rọ̀ mi fún ilé Israẹli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.