Native Bible

Exodus 7:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọjọ́ méje sì kọjá ti Olúwa ti lu odò Naili.

Exodus 7:25 in English

Exodus 7:25 · Berean Standard Bible

And seven full days passed after the LORD had struck the Nile.

Context

23Dípò bẹ́ẹ̀, ó yíjú padà, ó sì lọ sí ààfin rẹ̀, kò sì jẹ́ kí àwọn nǹkan wọ̀nyí wà ni oókan àyà rẹ̀. 24Nígbà náà ni gbogbo àwọn ará Ejibiti bẹ̀rẹ̀ sí í gbẹ́ etí odò Naili láti wá omi tí wọn yóò mu, nítorí wọn kò le è mu omi tí ó wà nínú odò náà. 25Ọjọ́ méje sì kọjá ti Olúwa ti lu odò Naili.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.