Native Bible

Exodus 6:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Isari ni: Kora, Nefegi àti Sikri.

Exodus 6:21 in English

Exodus 6:21 · Berean Standard Bible

The sons of Izhar were Korah, Nepheg, and Zichri.

Context

19Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn. 20Amramu sì fẹ́ Jokebedi arábìnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jokebedi sì bí Aaroni àti Mose fún un. Amramu lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé. 21Àwọn ọmọ Isari ni: Kora, Nefegi àti Sikri. 22Àwọn ọmọ Usieli ni: Miṣaeli, Elsafani àti Sitiri. 23Aaroni fẹ́ Eliṣeba ọmọbìnrin Amminadabu tí í ṣe arábìnrin Nahiṣoni, ó sì bí Nadabu, Abihu, Eleasari àti Itamari.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.