Eksodu 6:19
Exodus 6:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Merari ni: Mahili àti Muṣi. Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn.
Exodus 6:19 in English
Exodus 6:19 · Berean Standard Bible
The sons of Merari were Mahli and Mushi. These were the clans of the Levites according to their records.
Context
17Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati ni:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé. 19Àwọn ọmọ Merari ni:
Mahili àti Muṣi.
Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn. 20Amramu sì fẹ́ Jokebedi arábìnrin baba rẹ̀ ní ìyàwó. Jokebedi sì bí Aaroni àti Mose fún un.
Amramu lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé. 21Àwọn ọmọ Isari ni:
Kora, Nefegi àti Sikri.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.