Eksodu 6:17
Exodus 6:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni: Libni àti Ṣimei.
Exodus 6:17 in English
Exodus 6:17 · Berean Standard Bible
The sons of Gershon were Libni and Shimei, by their clans.
Context
15Àwọn ọmọ Simeoni ni:
Jemueli, Jamini, Ohadi, Jakini, Sohari àti Saulu ọmọ obìnrin Kenaani.
Àwọn wọ̀nyí ni ìran Simeoni. 16Ìwọ̀nyí ni orúkọ àwọn ọmọ Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn:
Gerṣoni, Kohati àti Merari.
Lefi lo ẹ̀tàdínlógóje (137) ọdún láyé. 17Àwọn ọmọ Gerṣoni ni ìran wọn ni:
Libni àti Ṣimei. 18Àwọn ọmọ Kohati ni:
Amramu, Isari, Hebroni àti Usieli.
Kohati lo ẹ̀tàléláádóje (133) ọdún láyé. 19Àwọn ọmọ Merari ni:
Mahili àti Muṣi.
Ìwọ̀nyí ni ìran Lefi gẹ́gẹ́ bí àkọsílẹ̀ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.