Eksodu 36:22
Exodus 36:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì tí ó kọjú sí ara wọn. Wọ́n ṣe gbogbo pákó àgọ́ náà bí èyí.
Exodus 36:22 in English
Exodus 36:22 · Berean Standard Bible
Two tenons * were connected to each other for each frame. He made all the frames of the tabernacle in this way.
Context
20Ó sì ṣe pákó igi kasia tí ó dúró òró fún àgọ́ náà. 21Ọ̀kọ̀ọ̀kan pákó náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ní fífẹ̀, 22pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì tí ó kọjú sí ara wọn. Wọ́n ṣe gbogbo pákó àgọ́ náà bí èyí. 23Ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà. 24Ó sì ṣe ogójì fàdákà ihò ìtẹ̀bọ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ wọn ìtẹ̀bọ̀ méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìsàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.