Native Bible

Exodus 36:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà.

Exodus 36:23 in English

Exodus 36:23 · Berean Standard Bible

He constructed twenty frames for the south side of the tabernacle,

Context

21Ọ̀kọ̀ọ̀kan pákó náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ní fífẹ̀, 22pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì tí ó kọjú sí ara wọn. Wọ́n ṣe gbogbo pákó àgọ́ náà bí èyí. 23Ó sì ṣe ogún pákó sí ìhà gúúsù àgọ́ náà. 24Ó sì ṣe ogójì fàdákà ihò ìtẹ̀bọ̀ lọ sí ìsàlẹ̀ wọn ìtẹ̀bọ̀ méjì fún pákó kọ̀ọ̀kan, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní ìsàlẹ̀ ìtẹ̀bọ̀. 25Fún ìhà kejì, ìhà àríwá àgọ́ náà, wọ́n ṣe ogún pákó

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.