Native Bible

Exodus 36:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sì ṣe pákó igi kasia tí ó dúró òró fún àgọ́ náà.

Exodus 36:20 in English

Exodus 36:20 · Berean Standard Bible

Next, he constructed upright frames of acacia wood for the tabernacle.

Context

18Wọ́n ṣe àádọ́ta ìkọ́ idẹ láti so àgọ́ náà pọ̀ kí o lè jẹ́ ọ̀kan. 19Ó sì ṣe ìbòrí awọ àgbò tí a rì ní pupa fún àgọ́ náà, àti ìbòrí awọ seali sórí rẹ̀. 20Ó sì ṣe pákó igi kasia tí ó dúró òró fún àgọ́ náà. 21Ọ̀kọ̀ọ̀kan pákó náà jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ kan ààbọ̀ ní fífẹ̀, 22pẹ̀lú ìtẹ̀bọ̀ méjì tí ó kọjú sí ara wọn. Wọ́n ṣe gbogbo pákó àgọ́ náà bí èyí.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.