Eksodu 35:20
Exodus 35:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli sì kúrò níwájú Mose,
Exodus 35:20 in English
Exodus 35:20 · Berean Standard Bible
Then the whole congregation of Israel withdrew from the presence of Moses.
Context
18Èèkàn àgọ́ náà fún àgọ́ náà àti fún àgbàlá àti okùn wọn. 19Aṣọ híhun láti ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́ aṣọ mímọ́ fún Aaroni àlùfáà àti aṣọ fún àwọn ọmọ rẹ̀ nígbà tí wọ́n sìn bí àlùfáà.” 20Gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli sì kúrò níwájú Mose, 21olúkúlùkù ẹni tí ó fẹ́ àti ẹni tí ọkàn rẹ̀ gbé sókè wá, wọ́n sì mú ọrẹ fún Olúwa, fún iṣẹ́ àgọ́ àjọ, fún gbogbo ìsìn rẹ̀ àti fún aṣọ mímọ́ náà. 22Gbogbo àwọn tí ó fẹ́, ọkùnrin àti obìnrin, wọ́n wá wọ́n sì mú onírúurú ìlẹ̀kẹ̀ wúrà: òrùka etí, òrùka àti ọ̀ṣọ́. Gbogbo wọn mú wúrà gẹ́gẹ́ bí ọrẹ wá fún Olúwa.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.