Eksodu 35:18
Exodus 35:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èèkàn àgọ́ náà fún àgọ́ náà àti fún àgbàlá àti okùn wọn.
Exodus 35:18 in English
Exodus 35:18 · Berean Standard Bible
the tent pegs for the tabernacle and for the courtyard, along with their ropes;
Context
16Pẹpẹ ẹbọ sísun pẹ̀lú ojú ààrò idẹ rẹ̀, òpó rẹ̀ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀;
agbada idẹ pẹ̀lú ẹsẹ̀ rẹ̀. 17Aṣọ títa ti àgbàlá pẹ̀lú, ọ̀wọ́n àti ihò ìtẹ̀bọ̀ rẹ̀ àti aṣọ títa fún ẹnu-ọ̀nà àgbàlá náà. 18Èèkàn àgọ́ náà fún àgọ́ náà àti fún àgbàlá àti okùn wọn. 19Aṣọ híhun láti ṣiṣẹ́ ní ibi mímọ́ aṣọ mímọ́ fún Aaroni àlùfáà àti aṣọ fún àwọn ọmọ rẹ̀ nígbà tí wọ́n sìn bí àlùfáà.” 20Gbogbo ìjọ àwọn ọmọ Israẹli sì kúrò níwájú Mose,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.