Native Bible

Exodus 25:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ wọn: “wúrà, fàdákà àti idẹ;

Exodus 25:3 in English

Exodus 25:3 · Berean Standard Bible

This is the offering you are to accept from them: gold, silver, and bronze;

Context

1Olúwa sì wí fún Mose pé, 2“Sọ fún àwọn ọmọ Israẹli kí wọn mú ọrẹ wá fún mi, ìwọ yóò gba ọrẹ náà fún mi ni ọwọ́ ọkùnrin kọ̀ọ̀kan ti ọkàn rẹ bá fẹ́ láti fi fún mi. 3“Wọ̀nyí ni ọrẹ ti ìwọ yóò gbà ni ọwọ́ wọn: “wúrà, fàdákà àti idẹ; 4aṣọ aláró, elése àlùkò, òdòdó, ọ̀gbọ̀; irun ewúrẹ́. 5Awọ àgbò tí a rẹ ní pupa àti awọ ewúrẹ́ igbó; igi kasia;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.